English - Yorùbá Dictionary

Rab

Rabbi noun. /  olùkọ́ni, olùkọ́ òfin ni èdè júù.

Rabbit noun. /  ehoro.

Rabble noun. /  ọ̀pọ̀ ènìyàn alainilari.

Rabid adj. /  ṣiwèrè.

Race noun. /  eré ìje, iré sísá, ìran, ẹ̀yà. verb. / sá, sáré.

Racetrack noun. /  gbàngbà ìsúré ìjé.

Racism noun. /  ìwà ìkórira.

Racist noun. /  akórira ẹlòmíràn.

Radiance noun. /  ìtànmọ́lẹ̀, itanṣan.

Radiant adj. /  títànsán.

Rag noun. /  àkísà.

Rage noun. / ìrunú, ìbínú.

Raid verb. /  gbógun tì, rọlù. noun. / ìgbógun tì.

Rail noun. /  ọgbà irin tàbí igi ojú irin rélùwé.

Rain noun. /  òjò.

Rainbow noun. /  òṣùmàrè.

Raise noun. /  ìbùsí iye owó. verb. / gbé sókè, gbé dúró.

Ram noun. /  àgbò, ràgò.

Ram

Ramadan noun. /  oṣu awẹ mùsùlùmí.

Ramble noun. /  irin kakiri.

Random adj. /  alábàpàdé, láìròtẹ́lẹ̀.

Range noun. /  gígùn, ìnà, òkè gíga, iyeorísi.

Rank noun. /  ẹgbẹ́, ipò.

Ransom noun. /  ìràpadà, owó ìdásílẹ̀, ìràsílẹ̀, ìgbàsílẹ̀.

Rape noun. /  ìbálò obìnrin nítipá tàbí dandan.

Rapid adj. /  yára, kánkán.

Rapture noun. /  ayọ púpọ̀, ayọ àyọ̀jù.

Rare adj. /  sọ̀wọ́n, aìpọ̀.

Rash noun. /  èsú ara, sísú.

Rat noun. /  èkúté.

Rate noun. /  iye, òṣùwọ̀n.

Rather adv. /  kúkú, sànjù, bókànràn.

Ratify verb. /  pinnu, fi ohùn sí.

Ration noun. /  ónjẹ ò jọ àwọn ọmọ ogun.

Rational adj. /  ní iyè nìnú, lọ́gbọ́n nìnú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba