English - Yorùbá Dictionary

Qua

Quake verb. /  gbọ̀n, wariri, mì.

Quaking adj. /  gbígbọ̀n rìrì.

Qualification noun. /  ẹ̀rí, ìjẹri ìwà.

Qualify verb. /  múyé, yán.

Quality noun. /  ìwà, agbára, ìrí.

Qualm noun. /  aibalẹ̀ ẹ̀rí ọkàn.

Quandary noun. /  híhá sarin méjé, ìdàmú, ìsòro.

Quantity noun. /  títóbi, ìwọn, iye.

Quarantine noun. /  dídá ọkọ̀ dúró nítorí àisàn.

Quarrel noun. /  ìjà, asọ̀, gbólóhùn asọ̀. verb. / jà.

Quarrelsome adj. /  tí ó lè jà, oníjà, aláriwo.

Quarry noun. /  ihò ibití atí nfọ́ òkúta.

Quart noun. /  ìdámẹ́rin òsùwọ̀n.

Quarter noun. /  ìdámẹ́rin ohunkóhun,.

Quash verb. /  tẹ̀ mọ́lẹ̀, ṣẹ́gun, paná.

Quaver verb. /  gbọ̀n lóhùn.

Quay noun. /  èbúté, ibi ìgúnlẹ̀ sí.

Queen noun. /  ayaba.

Que

Queer adj. /  yatọ, ṣòdi.

Quell verb. /  mú dakẹ, pa rẹ.

Quench verb. /  pa ku, párun.

Querulous adj. /  ainitẹlọrun, ráhùn, rojọ́.

Query noun. /  ìbérè. verb. / ṣe ìbérè.

Quest noun. /  ìwákiri.

Queue noun. /  títò. verb. / tò.

Quick adj. /  yára, láyè, tàrà, tètè.

Quickly adv. /  yárayára, nísìsìyí, kíákíá.

Quiet adj. /  dákẹ́, ìdákẹ́jẹ́, jẹ́jẹ́.

Quit verb. /  fi sílẹ̀, kọ sílẹ̀, lọ kúrò.

Quite adv. /  pátápátá.

Quiz noun. /  ìdánwò kúkúrú, ìbérè. verb. / dánwò, se ìbérè.

Quota noun. /  ìpín.

Quotation noun. /  ọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bi enití o ṣọ̀rọ̀ ti sọ́ gan.

Quote verb. /  ìdíyelé ọjà, tún ọ̀rọ̀ ẹlomi wi.

Quoth verb. /  wipe.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba