English - Yorùbá Dictionary

Fun

Function noun. /  ìlò, agbára, òye.

Fund noun. /  ìkójọpọ̀ owó.

Fundament noun. /  ìdí.

Fundamental adj. /  ti ìpilẹṣẹ, pàtàkì.

Funeral noun. /  ìsìnkú.

Fungus noun. /  olú igi, olú.

Funnel noun. /  àtìrọ, arọ, ìrọ, iho efin.

Funny adj. /  oníyẹ̀yẹ́, pa ni lẹ́rin.

Fur noun. /  irun múlọ́múlọ́.

Furious adj. /  tìbínù.

Furnace noun. /  iléru.

Furnish verb. /  pèsè fún.

Furrow noun. /  aparo.

Further adv. /  ṣíwájú, lókèrè.

Fury noun. /  ìkannú, ìbínú, ìrunú.

Fuss noun. /  ìrọ́kẹ́kẹ́, aisimi.

Futile adj. /  lasan, laiwulo.

Future noun. /  ti ìgbà tí mbọ̀, ti ẹ̀yìn ola, ti ọjọ́ iwájú.

Gain

Gag noun. /  asọ ìrépé tí a fi bọ ènìàn lẹ́nu ko mọ ba sọ̀rọ̀.

Gain noun. /  èrè, ìfà. verb. / jèrè, rí gbà, rí se.

Gainsay verb. /  riwisi, sọrọ òdì si.

Gaiter noun. /  aṣọ ìwésẹ̀.

Gala noun. /  ìdárayá, àríyá.

Gale noun. /  afẹ́fẹ́ líle, atẹ́gùn líle, iji.

Gamble verb. /  ta tẹ́tẹ́.

Gambler noun. /  atatẹ́tẹ́.

Gambling noun. /  tẹ́tẹ́ títa.

Game noun. /  iré, ìṣ iré, ẹyẹ tí ọdẹ pa.

Gander noun. /  akọ pẹ́pẹ́yẹ.

Gang noun. /  ẹgbẹ́ tí ó so wọ́pọ̀ láti se nkan.

Gaol noun. /  ilé ẹ̀wọn, ilé túbú.

Gap noun. /  ihò, ẹlà, ìsán, àfo.

Garage noun. /  ilé ìpamọ́ ọkọ̀, ilé àtúnse ọkọ̀.

Garbage noun. /  ìdọ̀tí.

Garden noun. /  ọgbà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba