English - Yorùbá Dictionary

Free

Free adj. /  láìdè, aláìnídè. adv. / ọ̀fẹ́. verb. / sọ di ominira.

Freedom noun. /  òmìnira.

Freeze verb. /  dì.

Freight noun. /  ẹrù ọkọ̀.

Freighter noun. /  ọkọ̀ àkẹrù.

Frenzy noun. /  ìsínwín, ìṣiwèrè.

Frequency noun. /  ìgbàkúùgbà.

Frequent adj. /  nígbàgbogbo, nígbàkúùgbà.

Frequently adj. /  lemọ́lemọ́, léraléra.

Fresh adj. /  tútù, titun, àkọ̀tun.

Friday noun. /  ijọ́ kẹfà ọsẹ, Jímọ̀h.

Friend noun. /  ọ̀rẹ́, ẹnìkejì.

Friendly adj. /  ìfanimọ́ra.

Friendship noun. /  ìrẹ́, ìrẹ́pọ̀, ìbárẹ́.

Frigate noun. /  ọkọ̀ ogun.

Fright noun. /  ẹrú, ìfòyà.

Frighten verb. /  dẹrùba, dáyà-ja.

Frog noun. /  ọ̀pọ̀lọ́.

From

From prep. /  lọ́wọ́, kúrò, nínú, láti.

Front adj. /  iwájú.

Frost noun. /  òtútù níní.

Frosty adj. /  ní òtútù, òtútù jọ́jọ́.

Frown noun. /  ìbojújẹ́, ìbínú. verb. / bojújẹ́, bínú si.

Frozen adj. /  dídì.

Fruit noun. /  éso, ọmọ.

Frustrate verb. /  bà-jẹ́, yí-po, yẹ̀-pá, sọ di asán.

Frustration noun. /  ìbàjẹ́.

Fry verb. /  yan nínú epo, dín.

Fugitive noun. /  ìsánsá. adj. / lai dúró níbìkan.

Fulfil verb. /  mú ṣẹ.

Fulfilment noun. /  ìmúṣẹ .

Full adj. /  kún.

Fully adv. /  ni kikún.

Fume noun. /  èéfín, oru.

Fun noun. /  iré, ìṣiré, ẹ̀fẹ̀, àwàdà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba