English - Yorùbá Dictionary

XYZ

Xenophobia noun. /  ẹru tàbí ìkórira àwọn ènìyàn láti ìlú òdìkejì.

Xerox noun. /  ẹ̀rọ ìtẹ̀wé.

X-ray noun. /  ẹ̀rọ tón ya àwòrán inú ara.


Yacht

Yacht noun. /  ọkọ̀ ojú omi fún fàjì.

Yank verb. /  fà lẹkanna pẹ̀lú agbára.

Yard noun. /  àgbàlá, ọ̀pá ìwọn ẹlẹ́sẹ̀.

Yawn noun. /  yíyán. verb. / yán.

Yeah noun. /  bẹni, bẹ na ni.

Year noun. /  ọdún, osù méjìlá.

Yearly adv. /  lọdọdun, ti ọdọdun kan.

Yearn verb. /  se iyọnu si.

Yeast noun. /  ìwúkàrà.

Yell verb. /  ké ramúramù, bú, kọ. noun. / bíbú, kíkọ.

Yellow adj. /  pupa rúsúrúsú bí àwọ ìyeyè.

Yes adv. /  bẹ ni, òtọ, han.

Yesterday adv. /  àná, lánà.

Yet

Yet adv. /  síbẹ̀, síbẹ̀síbẹ̀, bí ó tilẹ̀ rí bẹ.

Yield noun. /  èrè, ẹsan iṣẹ́, ìkórè. verb. / fi padà, san.

Yolk noun. /  pupa inú ẹyin.

You pron. /  ìwọ, ọ, ẹyín.

Young noun. /  èwe, ọ̀dọ́, nkan tí kò tí dàgbà púpọ̀.

Your pron. /  tìrẹ, tiyín.

Yourself pron. /  ìwọ tìkararẹ, ẹyin tìkara yín.

Youth noun. /  ọ̀dọ́mọdé, èwe.

Youthful adj. /  ti ọ̀dọ́mọdé, nígbà èwe.

Zealous

Zealous adj. /  níní tara nínú ohun gbogbo.

Zealously adv. /  pẹ̀lú ìtara.

Zebra noun. /  egbin.

Zenith noun. /  sonso, ìparí, ote, ibití ó ga jùlọ.

Zero (0) noun. /  òdo, òfo.

Zigzag noun. /  ségesège, wọrọwọrọ.

Zoo noun. /  ilé nlá ìpamọ́ àti ìfihàn onírúrú ẹranko.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba