English - Yorùbá Dictionary

Vac

Vacancy noun. /  àyè, àfo.

Vacant adj. /  ṣófo.

Vacate verb. /  parẹ́, fi àyè sílẹ̀ fún, fi ipò sílẹ̀.

Vacation noun. /  ìsimi díẹ lẹ́yìn iṣẹ́, ọludé.

Vaccinate verb. /  gbà nanba, gbà abẹ́rẹ́ àjẹsára.

Vaccine noun. /  àjẹára.

Vacillate verb. /  mi siyin sohun, se iyemeji.

Vacuum noun. /  òfo, àlàfo, mọ́.

Vagabond noun. /  ipanle, isansa, alarinkiri.

Vagina noun. /  òbò.

Vagrant adj. /  rírìnkiri láiní ibùgbé.

Vague adj. /  àilẹ́sẹ̀nílẹ̀, àidúró níbìkan, ṣàidájú, ṣíkiri.

Vain adj. /  lófo, lásán, aláìnílárí, láinídì.

Vainglory noun. /  ògo asán.

Vale noun. /  àfonífojì òkè nlá.

Valediction noun. /  ìdágbére.

Valet noun. /  ọmọ ọ̀dọ̀ ọkùnrin tí ndúró ti ènìyàn.

Valiant adj. /  akọni, nígbòyà, lágbára.

Val

Valid adj. /  nipa, ti a fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀ nínú òtítọ́ nípa òfin.

Validity noun. /  agbára, ipá, agbára òfin.

Valley noun. /  àfonífojì, àfo ilẹ̀ lárín òkè méjì.

Valorous adj. /  nígboyà, láibẹru, alágbára.

Valor noun. /  ìgboyà, ìwà akọni.

Valuable adj. /  níyelórí, lérèlórí, oníyebíye, lówólórí.

Valuation noun. /  ìdíyelé, ìfowólé.

Value noun. /  iye, iye owó, rírí, iyì.

Van noun. /  ọkọ̀ akérò.

Vandalism noun. /  ìbàjẹ́ ohun ìní láinídì.

Vanguard noun. /  ẹgbẹ́ ti o ṣaju ogun.

Vanish verb. /  yọ sálọ, fò lọ, fẹ́ lọ, di asán, di òfo.

Vanity noun. /  òfo, asán, ládòfo, ìgbéraga.

Vanquish verb. /  ṣẹ́gun, borí.

Vantage noun. /  ànfàní, àye, ère, ìrọ̀rùn.

Vapid adj. /  láiní ẹ̀mí, ṣíṣọ ẹ̀mí nù.

Vapor noun. /  oru.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba