English - Yorùbá Dictionary

Ubi

Ubiquitous adv. /  dàbí o wà níbi gbogbo nígbà kanna.

Ugly adj. /  burẹwà, lábùkù, lailẹwa.

Ulcer noun. /  egbò inú.

Ultimate adj. /  tí ó gbẹ̀hìn, tí ó jìnnà jùlọ, tí ó pin sí.

Umbrella noun. /  agbòrùn, agbòjò.

Unable adj. /  laileṣe, lailagbara.

Unacceptable adj. /  tí a kò lè gbà, tí kò si ọna níbẹ̀.

Unarmed adj. /  lainí nkan ìjà.

Unauthorized adj. /  lainí àṣẹ.

Unavoidable adj. /  lailèyẹ̀kúrò.

Unaware adj. /  láìròtẹ́lẹ̀, lójijì, láìmọ̀.

Unbearable adj. /  tí a kò lè faradà.

Unbelief noun. /  aigbagbọ.

Unbeliever noun. /  alaigbagbọ.

Uncertain adj. /  laidánilójú, síyèméjì.

Unclear adj. /  laimọ.

Uncomfortable adj. /  lairọrùn.

Uncommon adj. /  laiwọ́pọ̀.

Unc

Unconscious adj. /  laimọ̀ nínú, lailérò.

Unconsciously adv. /  láláimọ̀ nínú, láláilérò.

Uncontrol adj. /  láilè kóní janu.

Under prep. /  lábẹ́, nísàlẹ̀.

Underground adj. /  ìsàlẹ̀ ilé, abẹ́ ilẹ̀.

Underline verb. /  fa ilà sí lábẹ́.

Underneath adv. /  nísàlẹ̀, lábẹ́, abẹ́.

Understand verb. /  mọ̀, yé, gbọ yé.

Understandable adj. /  ti mímọ̀, ti yíyé.

Understanding adj. /  ti òye.

Undertake verb. /  dáwọ́le.

Underwater adj. /  lábẹ́ omi, nínú omi.

Underwear noun. /  àwọ̀tẹ́lẹ̀.

Undesirable adj. /  tí kò wuni.

Undiscovered adj. /  kò tí jágbọ́n.

Undress verb. /  bọ sọ, bọ láÿọ, bọ́rasílẹ̀, bọ́ra.

Uneasy adj. /  láirọrùn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba