English - Yorùbá Dictionary

Tab

Table noun. /  àga tábìlì, eto.

Tablecloth noun. /  aṣọ ìtẹ́lórí tábìlì.

Tabloid noun. /  ìwé ìròyìn kékeré pẹ̀lú àwòrán tó pọ̀.

Tacit adj. /  gbà laifọhun.

Tack noun. /  ìsó kékeré. verb. / sọ mọ, di mọ.

Tackle verb. /  kojú rẹ̀ láti gbà , bẹ̀rẹ̀sí ṣe nkan .

Tact noun. /  ọgbọ́n láti ma sẹ yan, ìmọ̀.

Take verb. /  ṣe, rà, rí gbà, ní.

Tale noun. /  ìtàn, àlọ́.

Talent noun. /  ẹ̀bùn Ọlọ́run, ẹ̀bùn àbínibí.

Talk noun. /  ọ̀rọ̀ ṣíṣọ. verb. / sọ, ṣọ̀rọ̀, wí, fọhùn.

Talkative adj. /  aláròyé.

Tall adj. /  gùn, gíga, gàgàrà.

Tame verb. /  tù lójú.

Tamper verb. /  tọwọbọ laiyẹ, fi ọwọ́ kan.

Tangle noun. /  kókó, ìdíjú, ìdamún, ìdàrú.

Tank noun. /  àgbá nlá.

Tanker noun. /  ọkọ̀ omi.

Tar

Tar noun. /  ọ̀dà. verb. / fi ọ̀dà kun.

Target noun. /  àmì fún ìbọn títa, ìpinu lìti dé bẹ̀.

Tariff noun. /  owò ọjà rírà, ìdíyelé nkan.

Task noun. /  iṣẹ́.

Taste noun. /  ìtọ́wò. verb. / tọwò.

Tasteful adj. /  ládùn, dùn.

Tasteless adj. /  láiládùn.

Tasty adj. /  àdídùn, ládùn.

Tax noun. /  owó sísan ìlú.

Tea noun. /  tii.

Teach verb. /  kọ lẹ́kọ, ọí níyè.

Teacher noun. /  olùkọ́.

Team noun. /  ẹgbẹ́, àkójọ ènìyàn láti se nkan.

Tear noun. /  ìfàya, omije, ẹkún. verb. / fàyaya.

Tease verb. /  tọ, yọ́ lẹ́nu.

Teenager noun. /  ọ̀dọ́mọbìnrin tàbí ọ̀dọ́mọkùnrin.

Telephone noun. /  ẹrọ ìbàniṣọ̀rọ̀, tẹlifónù.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba