English - Yorùbá Dictionary

Res

Resign verb. /  fi sílẹ̀, fi lé lọ́wọ́, síwọ́ iṣẹ́.

Resignation noun. /  ìfisílẹ̀, ìjọ́ lọ́wọ́.

Resist verb. /  kọjú ìjà sí, tàpá sí, takò.

Resistance noun. /  ìkọjújàsí, ìtàpásí, ìtakò.

Resolve verb. /  se àtúnse, pinnu.

Respect noun. /  àpónlé, ọ̀wọ̀, ìyìn.

Respectful adj. /  kún fún ọ̀wọ̀, tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀.

Respond verb. /  dá hùn, fèsì.

Response noun. /  ìdáhùn, èsì.

Rest noun. /  ìsimi, oorun ìdákẹ́.

Restless adj. /  láìnísimi.

Restoration noun. /  ìmúpadà sípò.

Restore verb. /  mú padà sípò, mu bọ sípò.

Restrict verb. /  pàlà fún, há mọ, fi mọ.

Restriction noun. /  ìpàlà, ìhámọ́, àlà.

Result noun. /  ìparí, ìyọrísí, òpin, èsì.

Resume verb. /  tún bẹ̀rẹ̀.

Retain verb. /  dá dúró.

Ret

Retake verb. /  tún mú, tún gbà.

Retaliation noun. /  ìgbẹ̀san.

Retention noun. /  ìdádúró, ìdílọ́wọ́, ìpamọ́.

Retire verb. /  lọ simi, ṣiwọ́ iṣẹ́.

Retract verb. /  yí ọ̀rọ̀ padà.

Retrain verb. /  tún kọ.

Retrieve verb. /  gbà padà.

Retrogress adj. /  ọlá nrẹyin.

Return noun. /  ìpadà, ìtúndé, àbọ̀. verb. / bọ̀, túndé, padà.

Reunion noun. /  ìpàdé lẹ́hìn ìpínyà.

Reuse verb. /  tún lò.

Reveal verb. /  ṣípaya, fihàn, ṣí sílẹ̀.

Revel noun. /  àríyá.

Revelation noun. /  ìfihàn, ìsípaya.

Revenge noun. /  ìgbẹ̀san.

Reverse noun. /  yi pada, parọ

Revert verb. /  padà sí, lé padà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba