English - Yorùbá Dictionary

Per

Period noun. /  àmí òpin, àkókò, ìgbà, nkan osù obìnrin.

Perjury noun. /  ìbúra èké.

Permanent adj. /  dúró pẹ́ títí, láìyẹsẹ.

Permissible adj. /  fún láyè, ìgbàfún.

Permission noun. /  àyè, ìbùnláyè.

Permit verb. /  gbà fún, bùn láyè. noun. / ìwé ìfàyèfún.

Persecution noun. /  inúnibíni, ìdálóró.

Persecutor noun. /  oninúnibíni.

Perseverance noun. /  ìdúró ṣinṣin, ìfórítì, ìtẹ́ramọ́.

Persist verb. /  tẹramọ́sé, forítì, dìmú ṣinṣin, fi àké kọ́rí.

Persistence noun. /  itẹramọ́sé, iforítì, ifi àké kọ́rí.

Persistent adj. /  ní ìtẹramọ, ní jàgùdà pálí.

Person noun. /  ènìyàn, ẹnìkan.

Personal adj. /  nípa ti ènìyàn.

Personality noun. /  ìwà.

Persuade verb. /  yí lọ́kàn padà, tàn, pa níyè dà.

Persuasion noun. /  ìyípáda ọkàn, ìpaléròdà, ẹtàn.

Persuasive adj. /  tí a lè yípadà.

Per

Pert adj. /  lafojudi.

Pest noun. /  àrùn, ìyọnu.

Pet noun. /  ohun ọsìn, àyànfẹ́, ìbínú. verb. / kẹ́, gẹ̀.

Pew noun. /  ìjóko nínú ilé Ọlọ́run.

Philosopher noun. /  ọlọ́gbọ́n, olùmọ̀, amòye, olùmọ̀ràn.

Philosophy noun. /  ìmọ, ọgbọ́n.

Phlegm noun. /  itọ ọfun, kẹ̀lẹ̀bẹ̀.

Pig noun. /  ẹlẹ́dẹ̀.

Pigeon noun. /  ẹyẹlé.

Pigmy noun. /  aràrá.

Pile verb. /  kó jọ, ko le ra wọn.

Piles noun. /  jẹ̀díjẹ̀dí.

Pilgrim noun. /  èrò, alárìnkiri, olùbẹ̀ ibi mímọ́ wò.

Pilgrimage noun. /  ibẹ̀ ibi mímọ́ wò.

Pillar noun. /  òpó.

Pillow noun. /  ìrọ̀rí, tìmtìm.

Pilot noun. /  atukọ̀, afọnàhàn nínú ọkọ̀, atukọ̀ bàlú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba