English - Yorùbá Dictionary

Nor

Northwards adv. /  níha àríwá.

Nose noun. /  imú.

Nostrill noun. /  ihò imú.

Not adv. /  kò, kì.

Notable adj. /  níyìn, lókìkí, àfiyèsí.

Notary noun. /  alámì ìjẹri ìwé, ìjẹri sí ìwé.

Note noun. /  ìwé owó, àmì orin, ìwé kúkúrú. verb. / kọ.

Notebook noun. /  ìwé ìfiyèsí, ìwé ìrántí.

Noteworthy adj. /  yẹ ni afiyèsí.

Nothing adv. /  àìsínkan, àìsí, àìwà, àìnílárí, ófo.

Notice noun. /  àfiyèsí, ìkìlọ̀, ìròhìn.

Noticeable adj. /  nífiyèsí.

Notification noun. /  ìkìlọ̀, ìfihàn.

Notify verb. /  sọ di mímọ̀, wí fún, kìlọ̀ fún.

Notion noun. /  ìmọ̀, irọ́.

Notorious adj. /  mímọ̀ ní gbangba, lókìkí.

Noun noun. /  orúkọ ènìyàn tàbí ti ohunkóhun.

Nourish verb. /  bọ, fi onjẹ fún, tọ dàgbà, kẹ.

Nov

Novel noun. /  ìwé ìtàn.

November noun. /  osù kọkànlá ọdún.

Now adv. /  ìgbà ìsisìyí, wàyí.

Nowhere adv. /  láìsíníbìkan.

Nozzle noun. /  imú, ẹnu.

Nude adj. /  níhòhò.

Nuisance noun. /  ìyọ́nu, ìrira, ìpanilára, ẹ̀gbin.

Number noun. /  iye.

Numerical adj. /  níye.

Nun noun. /  obínrin àlùfáà nínú ìjọ.

Nurse noun. /  olùtọ́, ọlójọ̀jọ̀ ọmọ, alágbàtọ́.

Nursery noun. /  ilé ìtọ́jú ọmọ wẹ́wẹ́.

Nursing home noun. /  ilé ìtọ́jú àwọn arúgbó.

Nursing noun. /  ìtọ́jú ìwòsàn.

Nurture noun. /  onjẹ, ẹ̀kọ́. verb. / kọ́, tọ, bọ́.

Nut noun. /  kóró éso igi, èkùrọ́, ẹ̀pà.

Nutrition noun. /  onjẹ, bíbọ́, àjẹsára.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba