English - Yorùbá Dictionary

Mac

Machete noun. /  àdá.

Machine noun. /  ẹrọ.

Machinery noun. /  ohun èlò.

Mad adj. /  ṣiwèrè, asínwín.

Made adj. /  ṣe, da.

Magazine noun. /  ìwé ìròhìn, àpò ẹtù.

Maggot noun. /  ìdin.

Maggoty adj. /  ṣedin, nìdin.

Magic noun. /  idán.

Magician noun. /  onídán.

Magistrate noun. /  onídájọ́.

Magnet noun. /  agbérin, òòfà.

Magnificent adj. /  tóbi, níyìn púpọ̀, lógo.

Magnify verb. /  gbé-ga, yìn lógo, mú-tóbi.

Maid noun. /  ọmọọ̀dọ̀ obìnrin, obìnrin, omidan.

Mail noun. /  lẹ́tà.

Mailbox noun. /  àpótí tí a nfi lẹ́tà pamọ́ sí.

Main adj. /  pàtàkì, olórí.

Main

Mainly adv. /  ní pàtàkì, pàtàkì jùlọ.

Maintain verb. /  tọ́jú, ṣe ìtọ́jú, dì mú.

Maintenance noun. /  ìtọ́jú.

Maize noun. /  àgbàdo.

Major noun. /  oyè ọ̀gágun àgbà. adj / pọ̀ jù, tóbi jù.

Majority noun. /  ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Make verb. /  ṣe, dá.

Male adj. /  akọ.

Malignant adj. /  ní ìkà, ní oró nínú.

Man noun. /  ọkùnrin àgbà.

Manage verb. /  to, ṣe ìtọ́jú, ṣe àbójútó, ṣe àkóso, kápá.

Manageable adj. /  níkáwọ́, rọrùn láti lò.

Management noun. /  ìbójútó.

Manager noun. /  alábójútó, olórí.

Mandate noun. /  àṣẹ, ofin.

Mondatory adj. /  àṣẹ dandan, àṣẹ ní túláàsì.

Mane noun. /  irun ọrun ẹsin tàbí kiniun.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba