English - Yorùbá Dictionary

Kitt

Kitten noun. /  ọmọ olóngbò, ọmọ olóngìnní.

Knead verb. /  pò.

Knee noun. /  orúkún, ekún.

Kneecap noun. /  egungun orúkún,.

Kneel verb. /  kúnlẹ̀.

Knife noun. /  ọ̀bẹ.

Knight noun. /  irú olóyè kan.

Knit verb. /  fi ọwọ́ hun, dàpọ.

Knob noun. /  kókó.

Knock verb. /  lù, kàn, kànkùn.

Knot noun. /  kókó, ìdìjú, ìsolù.

Knoll noun. /  oke kékeré.

Know verb. /  mọ̀.

Knowing adj. /  gbọ́n, mòye.

Knowledge noun. /  ìmọ, mímọ̀, ọgbọ́n, ẹ̀kọ́, òye.

Knuckle noun. /  oríìké ìka, kókó ẹyin ọwọ́.

Kola noun. /  obi, orógbó.

Koran noun. /  Àlkùránì, ìwé-mímọ́ ẹlẹ́sìn mùsùlùmí.

Label

Label verb. /  ìwé ti a nfi sàmi ẹrù.

Labour noun. /  iṣẹ́, lala, ìrobí.

Labourer noun. /  asisẹ́, alágbàse.

Lace noun. /  okùn bàtà, ìgbátí aṣọ.

Lacerate verb. /  ya, ṣalọ́gbẹ́.

Lack noun. /  aìni, aìto.

Lad noun. /  ọ̀dọ́mọkùnrin.

Ladder noun. /  àkàsọ̀, àkàbà.

Lady noun. /  ọ̀dọ́mọbinrin.

Lag verb. /  ṣe ilọra, fa sẹ́yìn.

Lagoon noun. /  ọ̀sa.

Lake noun. /  adágún.

Lamb noun. /  agutan.

Lame adj. /  amúkun.

Lamp noun. /  fìtílà, àtùpà.

Land noun. /  ilẹ̀.verb. / gúnlẹ̀.

Landing noun. /  igúnlẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba