English - Yorùbá Dictionary

Aa

Aback adv. / ìyàlẹ́nu, lójijì, láiròtẹ́lẹ̀.

Abandon verb. / fi sílẹ̀, kọ̀sílẹ̀.

Abandoned adj. / fifisílẹ̀, kikọ̀sílẹ̀ pátápátá.

Abandonment noun. / ifisílẹ̀, ikọ̀sílẹ̀ pátápátá.

Abate verb. / dínkù, fàsẹ́hìn, dáwódúró diẹ.

Abatement noun. / ídínkù, ifàsẹ́hìn, idáwódúró diẹ.

Abbey noun. / ilé àkọ́mọ́ iléìjọ́sìn.

Abbreviate verb. / gé kúrú, ṣẹ́kù.

Abbrevation noun. / ìgékúrú, ìṣẹ́kù.

Abdicate verb. / bọ́ oyè sílẹ̀.

Abdication noun. / ìbọ́ oyè sílẹ̀.

Abdomen noun. /  ikùn.

Abduct verb. / gbé sálọ , fà kúrò.

Abduction noun. / ìgbé sálọ , ìfà kúrò.

Abeyance noun. / ìdádúró.

Abhor verb. / kórira.

Abhorrence noun. / ìkórira.

Abide verb. / bá gbé.

Ability

Ability noun. / agbára, òyé.

Abjuration noun. / ìbúra, ìgégun.

Abjure verb. / fi-bú, fí gégun.

Ablaze adv. / gbiná.

Able adj. / lè, lágbára.

Ablution noun. / ìfomí-wẹnu pẹ̀lú ọwọ́ pẹ̀lú ojú, (àlùwàlá).

Abnormal adj. / ṣàjèjì, abàmì.

Aboard adv. / nínú ọkọ̀, sínú ọkọ̀.

Abode noun. / ìbùgbé, ibùjókò.

Abolish verb. /  pa-rẹ́, sọ-dasán, sọ-dòfo.

Abolition noun. / iparẹ́, isọ-dasán, isọ-dòfo.

Abominable adj. / rinilara, lẹ́gbin.

Abomination noun. / ẹgbin, ohun irira.

Aborigines noun. / ọmọ-ìbílè, onílẹ̀.

Abortion noun. / ìsẹ́yún, ṣíṣẹ́ oyún.

Abortive adj. / jásí asán.

Abound verb. / pọ̀, di pípọ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba