English - Yorùbá Dictionary

Imme

Immediate adj. /  lójúkanna, lọ́gán, kiakia.

Immediately adv. /  nísisìyí, wéréwéré, kóyákóyá.

Immense adj. /  láìníwọn, tóbi púpọ̀.

Immerse verb. /  tẹ bọmi.

Immersion noun. /  itẹbọmi.

Immigrate verb. /  ṣiṣilọ sí ìlú mi.

Immigration noun. /  iṣiṣilọ sí ìlú mi.

Imminent adj. /  léwu lórí, súnmọ ìtòsí.

Immoral adj. /  àgbèrè, láìníwà rere, buru.

Immortal adj. /  láìkú, tí kò lè kú.

Immortality adj. /  áìkú, àìdìbàjẹ́.

Immune adj. /  lánfàní, ìtúsílẹ̀.

Immunity noun. /  ànfàní, ìdásílẹ̀.

Impact noun. /  agbára kíkàn, ìwólù.

Impair verb. /  bàjẹ́, fàsẹ́hìn.

Impale verb. /  sọgbà yíká, sín.

Impartial adj. /  lótìtọ, láìní ojúsájú ènìyàn.

Impassable adj. /  láìṣé là kọjá.

Imp

Impatience noun. /  àìnísúrù, ìkánjú, àìfarabalẹ.

Impatient adj. /  láìnísúrù, níkánjú, láìfarabalẹ.

Imperial adj. /  ti ìjọbati ọba.

Implement noun. /  ohun ọnà, ohun èlo iṣẹ.

Implicate verb. /  lọlu, wẹ̀mọ́, lọ́wọ́ níní.

Implication noun. /  ilọ́wọ nínú nkan.

Implore verb. /  bẹ̀, bẹ̀bẹ.

Impolite adj. /  láìmòye, láìní ìwà rere.

Import verb. /  mú láti òkèrè wọ ìlú.

Importance noun. /  ohun pàtàkì, lárí.

Important adj. /  pàtàkì, tóbi, lárí.

Importer noun. /  oníṣòwò tí nmú ọjà òkèrè wọ ìlú.

Impossible adj. /  sòro, láìsése.

Impotence noun. /  àìlera òkùnrùn, òkóbó, akúra.

Imprison verb. /  há mọ, sé mọ , tí mọ lé.

Imprisonment noun. /  ìhámọ inú túbú, ìfisẹwọn.

Improper adj. /  láìtọ, láìyẹ.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba