English - Yorùbá Dictionary

Each

Each pron. /  ọkọkan, olúkúlùkù, ẹyọkọkan.

Eager adj. /  nítara, níwára.

Eagerly adv. /  pẹ̀lú nítara, pẹ̀lú níwára.

Eagle noun. /  ọrúkọ ẹyẹ kan tí ọ́ mọ́ ngbé ọmọ adìẹ.

Ear noun. /  etí, ṣirì-ọkà.

Earache noun. /  etí ríro, etí dídùn.

Early adj. /  kùtùkùtù, tẹ́lẹ̀, ní ìbẹ̀rẹ̀.

Earn verb. /  pa owó, jẹ, ṣiṣẹ́ owó, rí-gbà.

Earring noun. /  òrúka etí, yarini.

Earth noun. /  ayé, ilẹ̀, erùpẹ̀.

Earthquake noun. /  ilẹ̀ mímì, ìwàrìrì ilẹ̀, ilẹ̀ sísán.

Earthworm noun. /  ekòló.

Ease noun. /  ìrọra, àìnira, ìdẹra.

East noun. /  ìlà oòrùn, gàbasì.

Easter noun. /  ọjọ́ àjínde Krístì, àgbènde.

Eastern adj. /  nílà-oòrùn.

Eastward adv. /  níhà ìlà-oòrùn.

Easy adj. /  láìsòro, ní-rọ̀rùn, láìnira.

Eat

Eat verb. /  jẹ, jẹun.

Eatable noun. /  nkan jíjẹ.

Eavesdrop noun. /  ẹnití nfi etí mọ́ ògiri gbọ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀.

Echo noun. /  gbohùngbohùn.

Economic adj. /  nípa ọrọ̀-ajé.

Economy adj. /  mímọ owó tọ́jú.

Ecstacy noun. /  ayọ̀ ayọ̀ju, ayọ̀ púpọ̀.

Eczema noun. /  kòkòrò tó ma nyún yàn lára.

Edge noun. /  ojú ohun èlò, etí nkan.

Edit verb. /  ìyọkúrọ̀ tàbí ìfikún nkan bí ìwé kíkọ.

Edition noun. /  ṣíṣe ìwé.

Editor noun. /  ẹnití nse ìwé fún títẹ̀, olótùú.

Educate verb. /  kọ́ lẹkọ, tọ́, kọ́.

Education noun. /  ẹ̀kọ́.

Eel noun. /  ẹja tógùn tí ara rẹ tínrín.

Effect noun. /  èrè, èso iṣẹ, ìyọrísí.

Effective adj. /  wúlò, èyí tí yóò níyọrísí.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba