English - Yorùbá Dictionary

Dab

Dab verb. /  lù jẹ́jẹ́. noun. / lílù jẹ́jẹ́.

Dad noun. /  bàbá.

Dagger noun. /  ọ̀bẹ olójú méjì, idà kúkurú.

Daily adj. /  lójojúmọ́, ojojúmọ́, ọjọ́ gbogbo.

Daintily adv. /  yùngbà yùngbà.

Dairy noun. /  ilé isẹ́ tàbí ibití wón ti nta mílíkì pẹ̀lú bọ́tà.

Dam noun. /  síse ọ̀nà omi, dídarí omi ṣíṣàn.

Damage noun. /  òfò, ìbàjẹ́, àdánù, ìfarapa, jàmbá.

Damask noun. /  aṣọ ìṣẹ̀dá aláràbarà.

Damp adj. /  ọririn, òtútù, ìkúku, ọgìnnìtìn.

Dance verb. /  jó. noun. / ijó.

Dancer noun. /  oníjó, alájótà.

Dandle verb. /  gbé ọmọ ṣiré.

Dandruff noun. /  epa orí, eri orí, èkùsà.

Dandy noun. /  oge, onifari.

Danger noun. /  ìjàmbá, ewu.

Dangerous adj. /  léwu, ní ìjàmbá.

Dank adj. /  mótútù, lẹ́rọ̀fọ̀. noun. / ilẹ̀ ẹrọ̀fọ̀ nínú igbó.

Dare

Dare verb. /  gbodọ̀ dásà.

Daring adj. /  láyà, nígboyà.

Dark adj. /  ṣú, ṣókùnkùn, àìmòye.

Darken verb. /  ṣú òkùnkùn, ṣe àìmòye.

Darkness noun. /  òkùnkùn, aimoyé.

Darling noun. /  olùfẹ́.

Darn verb. /  rin aṣọ, tún ohun ti o fàya ṣe.

Dash verb. /  fọ́, kọlù, gbé ṣánlẹ̀.

Dastard noun. /  ojo. adj / ṣojo.

Data noun. /  àkójopọ̀ àwọn èdè tàbí ìmọ̀ràn tí o wúlò.

Date noun. /  àkókò, ọjọ́ tí nkan ṣe.

Daughter noun. /  ọmọ ti a bí ní obìnrin.

Dawn noun. /  àárọ kùtù, kùtù-kùtù, àfẹ̀mọ́júmọ́.

Day noun. /  ọjọ́, ọ̀sán.

Dead adj. /  kú, láìlẹmìí, di òkú.

Deadly adj. /  tí nmú ikú báni, pípani.

Deaf noun. /  adití. adj. / dití.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba