English - Yorùbá Dictionary

Can

Candidate noun. /  ẹnití nfẹ́ wọ inú ẹgbẹ́ tàbí iṣẹ́ kan.

Candle noun. /  àbẹ́là, fìtílà.

Candy noun. /  ohun àdídùn.

Cane noun. /  ọparun. verb. / nà.

Canister noun. /  agolo, páànù.

Cannibal noun. /  ajẹ̀nìyàn.

Cannibalism noun. /  jíjẹ ènìyàn, ìwà jíjẹ ènìyàn.

Cannon noun. /  ìbọn nlà, àgbá.

Cannot verb. /  kò lè, lailágbara.

Canoe noun. /  ọkọ́, ọkọ́ wétè, ìgbájá, ọ̀pẹ̀rẹ̀.

Canopy noun. /  ìbòrí tàbí aṣọ tí a ta sórí ìbùsùn.

Cant noun. /  ọ̀rọ̀ àgàbàgebè.

Cantonment noun. /  àdúgbò àwọn ọmọ ogun .

Canyon noun. /  ilẹ̀ jíjìn láarín òkè méjì.

Cap noun. /  ìderí,fìlà, ìborí.

Capability noun. /  agbára, àyè.

Capable noun. /  tó,lè, lágbára.

Capacious adj. /  tóbi,gbòrò, láyè.

Cap

Capacitate verb. /  fún ni agbára.

Capacity noun. /  agbára, ipá, àyè.

Cape noun. /  ṣónṣó ilẹ̀ tí ó yọrí sínú omi.

Capital noun. /  olórí, ìlù, olórí ìjọba ìlú, òkòwò.

Capitalism noun. /  nípa síse òwò ohun òkòwò.

Capitalist noun. /  olówó, ọlọ́rọ̀.

Capitulation noun. /  ìpinnu adehùn.

Capsize verb. / dojúdé, yípo, subú.

Captain noun. /  olórí ẹgbẹ́, ọ̀gákọ̀, ogágun, balógun.

Captive adj. /  ìgbèkùn, ondè, ẹlẹ́wòn.

Captivity noun. /  oko-ẹrú, ìkólẹrú.

Capture verb. /  mú ,fi agbára mú.

Car noun. /  ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́.

Caravan noun. /  ọkọ̀ aláfê.

Carbon noun. /  èkuru dúdú, èfín dúdú tí yo ní ìdí mọ́tò.

Card noun. /  ìwé pẹlẹbẹ, káàdì.

Cardboard noun. /  páálí.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba