English - Yorùbá Dictionary

Ban

Bang noun. /  lìlú.

Banish verb. /  lé lọ, lé kúrò ní ìlú, rán jáde.

Banishment noun. /  ilékúrò nílú.

Bank noun. /  bèbè, etí odò, ilé ifowó pamọ́.

Banker noun. /  ọ̀gá ilé ìfi owó pamọ́ sí .

Bankrupt noun. /  ajigbèsè, ẹnití owó bàjẹ́ mọ lọ́wọ́ .

Bankruptcy noun. /  ìbàjẹ́ owó.

Baptism noun. /  gbígba ènìyàn sínú ìjọ krístì.

Baptize verb. /  rì-sínú omi, rì bọ omi.

Bar noun. /  irin tàbi igi gbọrọ.

Barbarian noun. /  aláìgbédè, aláìmòye, ènìyànkénìyàn.

Barber noun. /  onígbàjámọ̀, fárífárí, agẹrun .

Bard noun. /  akéwì,akọrin, onírárà.

Bare adj. /  níhòhò, láìbò.

Barefoot adj. /  láìníbàtà, lẹ́sẹ̀ lásán, lẹ́sẹ̀ òfìfo.

Bargain noun. /  ìdùná-dùrà,ìpinnu, adehun.

Barge noun. /  ọkọ̀ ìgbájá.

Bark noun. /  gbígbó bí ajá,èpo igi. verb / gbó bí ajá.

Barn

Barn noun. /  àká, abà.

Barometer noun. /  ohun èlo láti fi wọ̀n afẹ́fẹ́.

Barrack noun. /  ilé àwọn ọmọ-ogun.

Barrel noun. /  àgbá.

Barren adj. /  yàgàn, ṣá,láìléso.

Barricade noun. /  ìdínà,ìsagbáradì.

Barrier noun. / ìdínà,agbára, àlà .

Barrister noun. /  agbẹjọ́rò, amòfin, lọ́yà .

Base noun. /  ìsàlẹ̀, ìpilẹ̀.

Baseborn adj. /  ọmọ àle.

Bashful adj. /  nítìjú, lójútì.

Basis verb. /  ìpilẹ̀.

Bask verb. /  yá orùn, yáná.

Basket noun. /  agbọ̀n, apẹ̀rẹ̀.

Bastard noun. /  ọmọ àle.

Bat noun. /  àdán .

Batch noun. /  àpopọ̀ nkan.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba